Question 4
- Kí ni Mọ́fíìmù?
- Pín ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sí mọ́fíìmù, kí o sì tọ́ka sí mọ́fíìmù ìpìlẹ̀ inú rẹ̀: (i) Ogbó (ii) Ọ̀pẹ́lẹ́ńgẹ́ (iii) etílé (iv) àìsí (v) ẹlẹ́ran
Observation
Candidates were required to define a morpheme in (a), and analyse words listed above into morphemes and identify the root/free morphemes in each word.
(a) Mọ́fíìmù ni ègé tàbí fọ́nrán tí ó kéré jù lọ tí ó sì ní iṣẹ́ tí ó ń ṣe tàbí ìtumọ̀ kíkún nínú ìhun ọ̀rọ̀.
(b) ọ̀rọ̀ Ìpín sí mọ́fíìmù Mọ́fíìmù ìpìlẹ̀ inú rẹ̀
(i) ogbó o - gbó gbó
(ii) ọ̀pẹ́lẹ́ńgẹ́ ọ̀ – pẹ́lẹ́ńgẹ́ pẹ́lẹ́ńgẹ́
(iii) etílé etí – ilé eti, ilé
(iv) aláta oní – a – ta ta
o-ní-a-ta ní, ta
(v) àìsì àì- sí/a-ì-sí sí
(vi) ẹlẹ́ran oní-ẹran ẹran
o-ní-ẹran ní, ẹran
Majority of the candidates recalled the definition of a morpheme in (a) but mistook morpheme for syllable in the analyses of the words listed in (b).