Question 5
Kọ wúnrẹ̀n aṣèbéèrè mẹ́wàá ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ kí o sì lo ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn nínú gbólóhùn.
Observation
Candidates were expected to itemise ten (10) interrogative words and use each of them in a sentence.
Wúnrẹ̀n aṣèbéèrè:
(i) Dà (ii) Ńkọ́ (iii) Ṣé (iv) kí
(v) Ǹjẹ́ (vi) Ta (vii) Èló (viii) Bí
(ix) Níbo (x) Wo (xi) Mélòó (xii) Báwo
(xiii) Tàbí/Àbí (xiv) Ńdan (xv) Èwo (xvi) kelòó
(xvii) Ẹ̀kelòó (xviii) Ibo (xix) Dan (xx) kẹ̀
(xxi) na (xxii) tíì (xxiii) Ṣèbí/Ṣebí
Candidates performed very well in answering this question.