Question 2
Lo bátànì FKF láti hun ọ̀rọ̀ Yoruba mẹ́wàá, kí F1 jẹ́ ;i’ láì lo fáwẹ̀lì kan gẹ́gẹ́ bí F2 lẹ́mẹ̀ẹjì
Observation
Candidates were required to use the pattern of F1 k F2 (vowel +consonant + vowel) to generate 10 words using alphabet ‘i’ as F1.
Àwọn ọ̀rọ̀ Yorùbá tí a fi bátànì F1KF2 hun: tí F1 jẹ́ ‘i’
Ìlù, ìlu, ijó, ìgbì, ike, irin, ìṣẹ́, iṣẹ́, ìrù, ibi, ìbí, ibí, ibo, ìbò, iṣu, iyọ̀, iwin, iyán
Many of the candidates who attempted this question could not use the appropriate tone marks on the words generated, this led to poor performance.