Yoruba Paper 2 WASSCE (PC 1ST), 2020

Question 4

(a) Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-ìṣe kíkún nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn gbólóhùn wọ̀nyí

Observation

Candidates were required to identify the main verb in each of the sentences.

 

       Ọ̀rọ̀-ìṣe kíkún inú gbólóhùn kọ̀ọ̀kan:


S/N

GBÓLÓHÙN

Ọ̀RỌ̀-ÌṢE KÍKÚN INÚ RẸ̀

a.

Olú kò dé Ifẹ̀ rí.

b.

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kan ń pa àtẹ́wọ́

pa

d.

Ẹ ò lè wọ ilé yìí o.

wọ/wọ̀

e.

Wọ́n dédé jùmọ̀ ń kọ orin.

kọ

ẹ.

Tóbi sáré jẹ ẹ̀bà rẹ̀ nítorí ẹ̀gbọ́n rẹ̀.

jẹ

f.

A pàdé wọn lọ́nà.

pàdé

g.

Kòkòrò ti ba ọ̀gẹ̀dẹ̀ náà jẹ́.

bàjẹ́

gb.

Má ṣe gbàgbé ọ̀rọ̀ yẹn.

gbàgbé

h.

Ọbẹ̀ náà korò gan-an.

korò

i.

Ẹ pẹ̀lẹ́ o.

pẹ̀lẹ́

 

Many of the candidates who attempted to identify the main verb in each sentence performed fairly well.