Yoruba Paper 2, Private Candidates 2019

Question 12

 

  1. Sọ pàtàkì àṣà ilà ojú kíkọ láààrín àwọṅ Yorùbá ní ayé àtijọ́.
  2. Dárúkọ́ àwọn ilà ojú wọ̀nyí:

Observation

 

Candidates were required to state the importance of tribal marks among the Yorubas in the olden days in (a) and to name tribal marks illustrated in the images in (b).

(a) Pàtàkì ilà kíkọ láàárín àwọn Yorùbá ní ayé àtijọ́:
(i) Ó jẹ́ kí a mọ ìdílé tí ènìyàn ti wá.

(ii) Ó jẹ́ kí a mọ ìran tí ènìyàn ti wá.

(iii) Ó jẹ́ ọ̀nà ìṣaralóge/bíbu ẹwà kún ìrísí ènìyàn.

(iv) Ó jẹ́ kí a mọ ihà tí a lè kọ sí ẹni náà, b.a. ọmọ Olúfẹ̀ akéjì-ọ̀m̀ọ kò ṣeé mú bí olùwọ̀.

(b) Orúkọ àwọn ilà ojú wọ̀nyí:
(i) Àbàjà mẹ́rin-mẹ́rin

(ii) Gọ̀ǹbọ́

(iii) Pélé mẹ́ta

(iv) Àbàjà mẹ́rin pẹ̀lú bààmú

(v) Àbàjà mẹ́fà/ Àbàjà ọmọ-ọba.

(vi) Kẹ́kẹ́

Most candidates who attempted this question could not name the tribal marks. This led to poor performance.