Yoruba Paper 2, Private Candidates 2019

Question 3

 

(a) Ṣe àlàyé ṣókí ṣókí lórí àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyí:

(i) Fóọ̀nù;
(ii) Fóníìmù;
(iii) Ẹ̀dà Fóníìmù;
(iv) Ìró Kọ́nsónáǹtì;
(v) Ìró fáwẹ̀lì.

(b) Fí àpẹẹrẹ méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ̀ ní 3(a) lẹ́sẹ̀

Observation

 

Candidates were tasked to give short description of the phonological terms in (a) and two examples of each term in (b).


  1. Few of the candidates performed fairly well in this question.
  2. Correct examples were given for iv and v but they missed out examples for i, ii and iii thus performing below expectation.