Yoruba Paper 2, Private Candidates 2019

Question 2

 

Ṣe àpèjúwe àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí: u, i, a, o, ẹ. an, ẹn, ọn, in, un.
Candidates were required to describe the vowels listed above.

Àpèjúwe àwọn ìró fáwẹ̀lì

(i) / u / fáwẹ̀lì òkè/àhánupè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè

(ii) / i / fáwẹ̀lì òkè/àhánupè iwájú pẹrẹsẹ àìránmúpè

(iii) / a / fáwẹ̀lì odò/àyanupè àárín pẹrẹsẹ àìránmúpè

(iv) / o / fáwẹ̀lì ẹ̀bákè/àhánudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè

(v) /ẹ / fáwẹ̀lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àìránmúpè

(vi) / an / fáwẹ́lì odò/àyanupè àárín pẹrẹsẹ àránmúpè

(vii) / ẹn / fáwẹ́lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè

(viii) / ọn / fáwẹ́lì ẹ̀bádò/àyanudíẹ̀pè ẹ̀yìn roboto àránmúpè

(ix) / in / fáwẹ́lì òkè/àyanupè iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè

(x) / un / fáwẹ́lì òkè/àhánupè ẹ̀yìn roboto àránmúpè

Observation

 

Many of the candidates who attempted this question could not give detailed description of the vowels.