Question 10
Nínú ewí Èèpà Ń Para Rẹ̀”, àwọn wo ni akéwì fi wé èèpà?
Observation
Candidates were required to mention various people compared with the fleaas stated in the poem “Èèpà Ń Para Rẹ̀”.
Àwọn tí akéwì fi wé Èèpà nínú ewì “Èèpà ń para rẹ̀”:
- ọ̀dọ́kọ, aṣẹ́wó, olówò nàbì
- ológe òṣì, ológe òfò
- akẹ́kọ̀ọ́ tó ń mugbó mu sìgá
- akẹ́kọ̀ọ́ tó ń ṣèjàngbọ̀n
- elérépá òṣì
- ẹni tí ó ń kọrin jupájupá kiri
- afàìṣadélébọ̀ ná ilé àwọn fètò (sí ọmọ bíbí)
- akẹ́kọ̀ọ́ tó wọ ẹgbẹ́ òkùnkùn
- akẹ́kọ̀ọ́ tó ń tẹ fóònù dípò kó kàwé
- akẹ́kọ̀ọ́ tó ń gbé owó ilé-ẹ̀kọ́ ná
- akẹ́kọ̀ọ́ tí a ti lé ní ilé-ẹ̀kọ́ tí kò lọ sílé
- akẹ́kọ̀ọ́ tó ń tilé-ẹ̀kọ́ lọ polon̄go ìbò
- akẹ́kọ̀ọ́ ọ̀kàwé ṣe tọ́ọ̀gì òṣèlú
Candidates’ performance was poor, general guesses were made and not as evident in the text.