Question 3
(a) Kí ni Àrànmọ́
(b) Mẹ́nu ba oríṣi àrànmọ́ mẹ́ta kí o sì ṣe àpèjúwe ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn. Fi àpẹẹrẹ méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ lẹ́sẹ̀
Observation
Candidates were required to define assimilation in (a) and to mention three types of assimilation and give two examples for each in (b).
(a) Oríkì Àrànmọ́
Àrànmọ́ ni agbára tí ìró kan ní láti sọ ìró mìíràn di irú ara rẹ̀ (ní kíkún tàbí ẹlẹ́bẹ