Yoruba Paper 2 WASSCE (SC), 2022

Question 7

 

Nínú oríkì Ìran Olúpo, tọ́ka sí àwọn èèwọ̀ tí ọ̀kọrin mẹ́nu bà

Observation

 

Candidates were expected to mention the taboos associated with the lineage of Olúpo as evident in the oral poetry.

Àwọn èèwọ̀ tí ọ̀kọrin mẹ́nu bà nínú oríkì Ìran Olúpo:

  1. Ẹrú ò gbọdọ̀ duyè n’Ípo nílé Ọya
  2. Ìwọ̀fà ò gbọdọ̀ duyè L’ọyàn Mọ̀jẹ̀
  3. Ifá tó bí Olúpó kò gbọdọ̀ wẹṣẹ
  4. Ifá tó bí Ajagùnnà ò gbọdọ̀ wẹ kàn-ìn kàn-ìn
  5. Òrìṣà Àgìdì kì í jẹ èwú iyán
  6. Ajagùnnà ò gbọdọ̀ mumi Òyì
  7. Olúpo kì í M’ọ̀sin
  8. Wọn kì í yọ pélé n’Írèsé
  9. Aṣàgùntàn ò gbọdọ̀ rojúde/ròkè abọya

 

The few candidates who attempted this question performed poorly.