Question 4
(a)Ṣe ìtúpalẹ̀ ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn ìsàlẹ̀ wọ̀nyí sí:
(i) àpólà orúkọ nípò olùwà;
(ii) àpólà ìṣe
(I) Kọ́lá ọmọ ìyá ẹlẹ́bà dìde
(II) Mo rí Gómìnà ìpínlẹ̀ wa.
(III) Wọ́n jẹ ẹ́ níjọsí.
(IV) Ọmọ náà fẹ́ràn ọtí líle.
(V) Dókítà náà dé ate.
(b) Ṣe àtúpalẹ̀ ìhun àpólà ìṣe kọ̀ọ̀kan tí ó wà ní 4(a)
Observation
Candidates were expected to analyse the given sentences to noun phrases and verb phrases in (a) and analyse the pattern of the verb phrases in (b)
Ìtúpalẹ̀ gbólóhùn sí àpólà orúkọ ní ipò olùwà àti àpólà ìṣe àti ìhun àpólà ìṣe
S/N |
Gbólóhùn |
Àpólà orúkọ ní ipò olùwà |
Àpólà ìṣe |
Ìhun Àpólà ìṣe náà |
i |
Kọ́lá, ọmọ ìyá ẹlẹ́bà dìde |
Kọ́lá, ọmọ ìyá ẹlẹ́bà |
Dìde |
ọ̀rọ̀-ìṣe |
ii |
Mo rí Gómìnà ìpínlẹ̀ wa |
Mo |
rí Gómìnà ìpínlẹ̀ wa |
ọ̀rọ̀-ìṣe àti àbọ̀ |
iii |
Wọ́n jẹ ẹ́ ní ìjọsí |
Wọ́n |
jẹ ẹ́ (ní ìjọsí) |
ọ̀rọ̀-ìṣe àti àbọ̀ |
iv |
Ọmọ náà fẹ́ràn ọtí líle |
Ọmọ náà |
fẹ́ràn ọtí líle |
ọ̀rọ̀-ìṣe àti àbọ̀ |
v |
Dókítà náà dé ate |
Dókítà náà |
dé ate |
ọ̀rọ̀-ìṣe àti àbọ̀ |
Many of the candidates who attempted this question performed fairly well. Although, some of them failed to identify the qualifiers alongside the head of the noun phrases