Question 2
Pa àtẹ ìró fáwẹ̀lì àránmúpè Yorùbá kí o sì ṣe àpèjúwe àwọn ìró inú rẹ̀ lọ́kọ̀ọ̀kan, b.a. [o] fáwẹ̀lì àhánudíẹ̀pè/èbákè roboto àìránmúpè.
Candidates were required to draw the nasal vowel chart and describe each of the nasal vowels in the chart.
(a) Àtẹ ìró fáwẹ̀lì àránmúpè èdè Yorùbá
(b) [ ĩ ]: fáwẹ̀lì àhánupè/òkè iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè
[ ɛ̃ ]: fáwẹ̀lì àyanudíẹ̀pè/ẹ̀bádò iwájú pẹrẹsẹ àránmúpè
[ ã ]: fáwẹ̀lì àyanupè/odò ẹ̀yìn roboto àránmúpè
[ ũ ]: fáwẹ̀lì àhánupè/òkè ẹ̀yìn roboto àránmúpè
[ ɔ̃ ]: fáwẹ̀lì àyanudíẹ̀pè/ẹ̀bádò ẹ̀yìn roboto àránmúpè