Question 5 Fi àpẹẹrẹ mẹ́ta mẹ́ta ṣàlàyé ọ̀kọ̀ọ̀kan àtúnpín ìsọ̀rí ọ̀rọ̀-orúkọ wọ̀nyí:
- Pa àtẹ ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà àti ẹ̀yán
Candidates were required to draw a chart of pronouns in subject and qualifier position in (a) and use the pronoun qualifiers in illustrative sentences in (b).
Àtẹ ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà, ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán àti ìlò wọn nínú gbólóhùn:
(ai) Àtẹ Ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò olùwà
S/N |
ẸNI |
ẸYỌ |
Ọ̀PỌ̀ |
a |
kínní |
mo |
a |
b |
kejì |
o |
ẹ |
d |
kẹta |
ó |
wọ́n |
(aii) Àtẹ Ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán
S/N |
ẸNI |
ẸYỌ |
Ọ̀PỌ̀ |
a |
kínní |
mi |
wa |
b |
kejì |
rẹ/ẹ |
yín |
d |
kẹta |
rẹ̀/ẹ̀ |
wọn |
- Ìlò ọ̀rọ̀ arọ́pò-orúkọ ní ipò ẹ̀yán nínú gbólóhùn
- Ọmọ mi ni Adéolú.
- Ilé rẹ/ẹ ni mò ń bọ̀.
- Aṣọ rẹ̀/ẹ̀ mọ́ tónítóní.
- Ọkọ̀ wa kò sáré./Olú sùn sí ilé wa.
- Ẹ gba ẹ̀bùn yín.
- Ọ̀rọ̀ wọn kò tète yé mi.
Candidates failed to use the pronouns in illustrative sentences and this led to loss of marks.