Question 3
Bí a bá lo àrokò O fún ohùn òkè; A fún ohùn àárín àti I fún ohùn ìsàlẹ̀, kọ ètò ohùn fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.
(a) aṣọ
(b) ilẹ̀
(d) ọkọ́
(e) ọ̀kọ̀
(ẹ) ìgbá
(f) igbà
(g) àgbọn
(gb) ọrùn
(h) ọ̀rún
(i) ọrún
(j) èje
(k) agbọ́n
(l) ẹ̀fẹ̀
(m) àpá
(n) epo
Candidates were required to use letters O, A and I to decode the registered tone marks on each of the words. Only a few candidates attempted this question and their responses was poor.
ÈTÒ OHÙN FÚN ÀWỌN Ọ̀RỌ̀ NÍ LÍLO ÀROKÒ: A(ààrin/àárín), O(òkè), I(ìsàlẹ̀)
S/N |
Ọ̀rọ̀ |
Ètò Ohùn Rẹ̀ |
a |
aṣọ |
A A |
b |
ilẹ̀ |
A I |
d |
ọkọ́ |
A O |
e |
ọ̀kọ̀ |
I I |
ẹ |
ìgbá |
I O |
f |
igbà |
A I |
g |
àgbọn |
I A |
gb |
ọrùn |
A I |
h |
ọ̀rún |
I O |
i |
ọrún |
A O |
j |
èje |
I A |
k |
agbọ́n |
A O |
l |
ẹ̀fẹ̀ |
I I |
m |
àpá |
I O |
n |
epo |
A A |
Candidates who attempted this question could not decode the tone marks on each of the given words.