Question 2
Ṣàlàyé ìgbésẹ̀ fonólọ́jì tí ó wáyé nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan ìwọ̀nyí.
Observation
Candidates were required to identify and explain the phonological processes for the derivation of given words.
(a) ewé oko => ewéko: Ìpajẹ àti ìsúnkì
(b) pa ẹ̀gàn => pẹ̀gàn: Ìpajẹ àti ìsúnkì
(d) wárápá => wáápá: Ìpajẹ (r), ìsúnkì
(e) jọ̀wọ́ => jọ̀ọ́ Ìpajẹ (w), ìsúnkì
(ẹ) kú alẹ́ => káalẹ́: àrànmọ́ ẹ̀yìn (ú di á)
(f) ìwé ilé => ìwéelé: Àrànmọ́ iwájú e i
(g) Kẹ́hìndé/Kẹ́yìndé => Kẹ́ìndé: Ìpajẹ (h/y), ìsúnkì
(gb) adìyẹ/adìrẹ => adìẹ: Ìpajẹ (y/r), ìsúnkì
(h) gbárìyẹ̀ => gbárìẹ̀: Ìpajẹ (y), ìsúnkì
(i) Èkùrọ́ => èkùọ́: Ìpajẹ (r),ìsúnkì
Many Candidates gave the correct input but failed to identify the phonological processes involved in the derivation of the given words.