Question 5
- Pe àkíyesi alátẹnumọ́ sí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fọ́nrán ìhun tí a fàlà sí ní ìdí nínú gbólóhùn wọ̀nyí.
- Dárúkọ àpólà kọ̀ọ̀kan tí a fàlà sí ní ìdí nínú àwọn gbólóhùn wọ̀nyí.
Observation
Candidates were required to generate emphatic sentences using the underlined items in the sentences in (a) and identify the type of phrases underlined in each sentence in (b).
(a) Pípe Àkíyèsí Alátẹnumọ́ sí fọ́nrán ìhun tí a fàlà sí ní ìdí nínú gbólóhùn:
(i) Oko ẹgàn ni Wọlé lọ.
(ii) Kíkọ́ ni Bánkẹ́ kọ́ ilé pẹ̀tẹ́ẹ̀sì.
(iii) Dídùn ni iṣu ewùrà máa ń dùn.
(iv) Èmi ni mo /ó se ọbẹ̀.
(v) Títí ni ó pọ́n omi.
(b) Awọn àpólà tí a fàlà sí ní ìdí nínú gbólóhùn:
- Àpólà àpọ́nlé
- Àpólà ìṣe
- Àpólà orúkọ
- Apólà orúkọ
- Àpólà atọ́kùn
(a) Many candidates generated emphatic sentences using the underlined items in the given sentences.
(b) Only a few candidates identified the types of phrases underlined in the given sentences.