Question 4
(a) Pín ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sí mọ́fíìmù.
(b) Lo márùn-ún nínú àwọn ọ̀rọ̀ tí ó wà ní (a) nínú gbólóhùn láti fi ìtumọ̀ ọkọ̀ọ̀kan wọn hàn.
Observation
Candidates were required to analyze given words into morphemes in (a) and use five of the given words in sentences to show the meaning of each word in (b).
ọ̀rọ̀ Ìpín sí mọ́fíìmù
- Adití a + di + etí
- À̀ìgbọ́fá àì + gbọ́ + ifá/ à + ì + gbọ́ + ifá
- Ẹlẹ́jọ́ oní + ẹjọ́/ o + ní + ẹjọ́
- Àṣàkaṣà àṣà + kí + àṣà
- Abúlésábúlé abúlé + sí + abúlé
- Ojoojúmọ́ ojú + mọ́ + ojú + mọ́
- Kólẹ̀kólẹ̀ kó + ilẹ̀ + kó + ilẹ̀
- Owóolé owó + ilé
- Pípọ́n pí + pọ́n
- Motúnráyọ̀ Mo + tún + rí + a + yọ̀
In (a), most candidates mistook syllable for morpheme and this led to poor performance. They however tackled the (b) aspect well.