Question 3
Kọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ní ìlàna ìdàkọ fóníìmù èdè Yorùbá.
Observation
Candidates were tasked to write the phonemic representation of the given words.
(a) Ìgbọràn /ìgbɔ̄rã̀/
Ìgbọnràn /ìgbɔ̃̄rã̀/
(b) Ìgbàgbọ́ /ìgbàgbɔ́/
(d) Ọgbọọgbọ́n /ɔ̄gbɔ̄ɔ̄gbɔ̃́/
(e) Ìfẹ́ /ìfɛ́/
(ẹ) Àbá /àbá/
(f) Fúnn̄kẹ́ /Fṹn̄kɛ́/
(g) Ọ̀pọ̀lọpọ̀ /ɔ̀kpɔ̀lɔ̄kpɔ̀/
(gb) Ọjà /ɔ̄ʤà/ /ɔ̄jà/
(h) Pańpẹ́ /kpāńkpɛ́/
(i) Àṣeyọrí /àʃejɔrí/
Most candidates failed to tone mark their phonemic representation and this led to loss of marks